- Angélique KidjoMostrar Notícias
- Aqui você curte Angélique Kidjo e seus Sucessos, Antigas, Novas e os Lançamentos.
- Quem ouve Angélique Kidjo tambem ouve:
- Essa semana a música mais ouvida é bahia - Angélique Kidjo
clique para tocar
bahia
Angélique Kidjo
Aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka loléAburo, ibi kan ni wao, kamura si ifè
Ouidah ni ilé ti bahia
Ti émin mon wa, ri yin lénin o
Bahia, bahia, bahia, bahia, bahia, bahia
Ilé ti babawa djinan, awa fè lolé
Bahia ilou ti awa lenin, okpè gan si ilé
Ogun ti awon agbalagba, shé kalè foun wa o
Logbé wa lo si bahia, gbé gbogbowa kpo
Bahia, bahia, bahia, bahia, bahia, bahia
Odjo ikadé wa m'bowa o, ti ale rira wa
Ewa ka moura foun odjo yin, ninou oyaya
Oluwa foun wa ni ayé, edjè ka du kpè
Bahia kpa gbogbowa kpo, iréti wa lonan
Aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé
Aburo, ibi kan ni wao, kamura si ifè
Ouidah ni ilé ti bahia
Ti émin mon wa, ri yin lénin o
Oré ifé ayé ilé, oré ifé ayé ilé...
Aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé
Aburo, ibi kan ni wao, kamura si ifè
Ouidah ni ilé ti bahia
Ti émin mon wa, ri yin lénin o
Oré ifé ayé ilé, oré ifé ayé ilé...